Apostle Ruben Agboola JP - Gbogbo E ni [Original]

Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Ìno ni ó jọ ọ̀tá ilé Bàbá
Ìno ni ó jọ ọ̀tá ilé Màmá tóbí mi (Ìno ni ó jọ ọ̀tá ilé Màmá tóbí mi)
Nínú ayé
Ẹnì tó fi ẹrin bá mi jà (ohhhh, ohhh, ohh, oh)
Awọn ti wọn fi ẹrin dá mi lóró
Igbe rárà lára ké wọlé (ahhhh lára ké wọlé)
Jẹ́kó sunkún jáde láyé

Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Ó ṣe bí ọrẹ ṣé ibì, Ọ̀tá mi lọ jẹ
Ó ṣe bí ènìyàn pàtàkì ó ní mi lara
Ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Jẹkó sunkún jáde láyé

Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ̀tá mi bá fẹẹ yo kondo
Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ̀tá mi bá fẹẹ yo kondo
Ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
Awọn arògó bo gó je

Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ̀tá mi bá fẹẹ yo kondo
Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ̀tá mi bá fẹẹ yo kondo
Ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
Awọn arògó bo gó je

Ọlọ́run mi
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọlé (ahhhh lára ké wọle)
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ́gbọ́ ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọlé
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Jékọ́ sunkún jáde láyé
Jékọ́ sunkún jáde láyé
Jékọ́ sunkún jáde láyé
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Àní ní lara ilẹ̀ Bàbá mi yẹn
Jẹkó sunkún jáde láyé

Written by:
Apostle Ruben Agboola JP

Publisher:
Lyrics © Brizzle Man

Lyrics powered by Lyric Find

Apostle Ruben Agboola JP

Apostle Ruben Agboola JP

View Profile