Apostle Ruben Agboola JP - Mo ni ki ndupe [Original]

Ko ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Ko ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Ko ni dúpẹ́
Mo ko ni dúpẹ́
Mo ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Ágbáni lágbá tón ni
Òré olódodo ní
O dabo bomi o
Ọtun pọn mí lé

Ko ni dúpẹ́
Mo ko ni dúpẹ́
Mo ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Kí gbọ́gbọ́ ènìyàn gbé ga
Kí gbọ́gbọ́ ẹ̀yán gbé ga
Fun ẹnì tó kú nítorí wá o
Àpáta ayérayé
O jìyà nítorí wá
Nítorí gbọ́gbọ́ ènìyàn ní
O fẹ mi rẹ lèlé
Ẹ̀jẹ̀ kí a dúpẹ́ ọ̀rẹ́ tí Jésù se

Ko ni dúpẹ́
Mo ko ni dúpẹ́
Mo ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Há! ẹgbẹ́ mí é w'asia
Bí tí nfẹ lélẹ̀
Ogún Jésù fèrè dé náà,
A'fere ségun (A'fere ṣẹ́gun)
D'odi mù, Ẹ̀mí fẹrẹ dé (D'odi mù, Ẹ̀mí fẹrẹ dé)
Beni Jésù nwi (Beni Jésù nwi)
Rán'dáhùn padà s'orun, pé (Rán'dáhùn padà s'orun, pé)
Àwa ọ dí mú (Àwa ọ dí mú)

Ko ni dúpẹ́
Mo ko ni dúpẹ́
Mo ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Ko ni dúpẹ́
Mo ko ni dúpẹ́
Mo ni dúpẹ́
Mo kọ ní dúpẹ́ ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ ni dúpẹ́ ni

Written by:
Apostle Ruben Agboola JP

Publisher:
Lyrics © Brizzle Man

Lyrics powered by Lyric Find

Apostle Ruben Agboola JP

Apostle Ruben Agboola JP

View Profile