OMONIYI OPEYEMI JTM MUSIC - Nigeria

Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Ilu to nsan fun wara, ilu to nsan fun oyin
Nigeria ilu olokiki
Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Ilu to nsan fun wara, ilu to nsan fun oyin
Nigeria ilu olokiki

Ile baba omo kii ba omo leru o
Ayunlo atayunbo lowo nyun enu
Ma sowo ma jere, ma rere oja je
Ma sori ire ni ile yi o
Ile baba omo kii ba omo leru
Ayunlo ayunbo lowo nyun enu
Ma sowo ma jere, ma rere oja je
Ma sori ire ni ile yi o

Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Ilu to nsan fun wara, ilu to nsan fun oyin
Nigeria ilu olokiki

Ni Nigeria yi o gbogbo e lo ma dara
Taba fowo sowopo o dami loju a to ra won
Ogun kosikosi ija lojojumo o maa dopin
Ejeka nife arawa ki Nigeria o toro
Ni Nigeria yi o gbogbo e lo ma dara
Taba fowo sowopo o dami loju a to ra won
Ogun kosikosi ija lojojumo o maa dopin
Ejeka nife arawa ki Nigeria o toro

Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Nigeria my country Nigeria ilu olokiki
Ilu to nsan fun wara, ilu to nsan fun oyin
Nigeria ilu olokiki

Gbogbo olori pata egbo labare yi o
Asiwaju le je e dari wa sibi to da
Ema fi dudu pe funfun tori pe efe terayin lorun o
Ema dariwa sigbo, e tun Nigeria se
Gbogbo olori pata egbo labare yi o
Asiwaju le je e dari wa sibi to da
Ema fi dudu pe funfun tori pe efe terayin lorun o
Ema dariwa sigbo, e tun Nigeria se
O God of creation, direct our noble cause
Guide our leaders right
Help our youth the truth to know
In love and honesty to grow
And live in just and truth
Great lofty heights attain
To build a nation where peace
And just shall reign.
Nigeria si ma dara o -Ilu olokiki
Nigeria si ma lewa gan - Ilu olokiki
Ile baba wa o o maa dara - Ilu olokiki
Mo nile mama yi a ku dara - Ilu olokiki
Mo ni gbogbo ona awa se regi - Ilu olokiki
Mo ni ina ijoba awa ni gbogbo igba - Ilu olokiki
Mo ni aa omi yala yolo ree - Ilu olokiki
Amaaa ladari rere - Ilu olokiki
Awon adari moni ti o ko owo wa je - Ilu olokiki
Awon adari o ti kii paro- Ilu olokiki
Nigeria si ma dara o - Ilu olokiki
Nigeria si ma lewa gan- Ilu olokiki
Nigeria temi mo yi ti mo ngbe - Ilu olokiki
Nigeria ta bimi si ilu baba mi ni - Ilu olokiki
Nigeria si ma dara aaaa- Ilu olokiki

Written by:
Opeyemi Omoniyi

Publisher:
Lyrics © O/B/O DistroKid

Lyrics powered by Lyric Find

OMONIYI OPEYEMI JTM MUSIC

View Profile