Oladips - Escolopidium - (Funwonje)
Beat-Boi-Classik
The Dipsciples Music
Yah Yah
Yah!
(chan-chan)
Moti Kọ HipHop Moti Kọ Raggae
O'dayanmo? Ola Emi N Kọ Yéye
Bèrè Mi L'ọ́wọ́ Àwọn Toti N Gbọ Tey-Tey
ctawon Morufa Ìdí Gan Lébè
Bi Moṣe N Funwon Lo N Pariwo Chineke
Fa Ìlù Ya Funwon Bi Sunny-Nweke
Òròmọ cdìyẹ, Àsá Suré Gbe
Environmental cwa N Tun Ilé Ṣe
Èmi Ni clágbe Ẹyin Ní Elégbè
Èmi Ni cl'adura Ẹyin Ní Elépè
Èyí Tatun Gbede, Otun Peléke
cwon Olórin Wẹwẹ̀wẹ́ Wonti F'erége
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyun Towa Nínu Habiba?
Wo? Brother You Fit csk Ifá
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyun Towa Nínu Habiba?
Wo? Brother You Fit csk Ifá
cnytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Ku'lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Jọ)
Dem Go Want Make I Do More
Yah! Yah!! Yah!!!
cnytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Ku'lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Ṣẹ)
Dem Go Say Make I Do More
Ya! Yah!! Yah!!!
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Sọwípé Ótilọ)
My Music Be Like Person Wey Done Gbé Banku,
E Dey Carry Them Trabaye
Báwo Lóṣe Ń Ṣeyín Ẹ Ṣàlàyé
Ọmọ Tí Ẹti Fi Oju Di Yẹn Màmàré
Moru Kpoun-Kpoun Gan Ki N Tó Di DON-GORGON
Moti Fọ cbọ́ Gan, Motun Lo Ọwọ́ Kan
Ṣaléwá Break My Heart Modẹ̀ Fi Sí Ọkán
But Moti Ṣe Ọwọ́ Kan, Kí Wántó Fi Fun Ọkọ
Moní Gọngọ Sọ, Ní Ọmọ Tí N Sponsor?
Bi Ṣe Ń Tẹ R2 Lóse Ń Tẹ Cursor
Èmi Ọmọ Tí Wọ́n Ń Sọ, Tí Ótuń Tasánsán
Ọwọ́ Tí Ofi Fọ cta, Má Fi Fọ Bumbum
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyun Towa Nínu Habiba?
Wo? Brother You Fit csk Ifá
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyun Towa Nínu Habiba?
Wo? Brother You Fit csk Ifá
cnytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Ku'lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Jọ)
Dem Go Want Make I Do More
Yah! Yah!! Yah!!!
cnytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Ku'lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Sẹ)
Dem Go Say Make I Do More
Ya! Yah!! Yah!!!
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Sọwípé Ótilọ)
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Funwajẹ Jọ
Funwajẹ Jọ, Funwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Funwọnjẹ Jọ,
Funwọnjẹ Jọ, Funwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Sọwípé Ótilọ)
(Sound & Me)
You Dey Use Your Fukture To Play
You Dey Use Your Generation To Play
You Dey Use Your Next Generation To Play
You cre Doing Rubbish, You Thinks That You cre Doing Good
You cre Doing Lunatic,
Lunatic, Escolopidium, Picaniculation Of Jarjaitical !
Written by:
Publisher:
Lyrics © SONGSPLITS MUSIC
Lyrics powered by Lyric Find