Poptyofv featuring Tat Lyricsane - Destiny

Òrí o
Destiny
Òrí
Ha
Orí là bá bo àbá fòrìshà sílè
Destiny tèmi yàtò kìn sé nkan tánlè kòsílè
Hmm opé ni fún eléèdá kòfi mí sìlé
Bóse ń se ìké lón sègbè léhìn
Wón ní mòńlo ìbílè ha
Orí mi orí àpésìn
Se omo ológo mi lórí olà kán má fimí sèsín
Ti'nbá lu kó ma dún kó ma já si
Mofé lówó lówó ju sèkèrè bí Don Jazzy
Level tí mo wà ti súnmi mofé shop up
Gbogbo ìfàséhìn pátá láiyé mi ni mofé pack up
Mofé lu àlùyo kin ma fò lókè
Kin ma se omo aráiyé lóore kówómi mú òkè
Mofé big position kin ma control
Fi àwon òtá mi guard mi kán lè ma bámi patrol
Ìyanu re jékó selè làiyè mi
Nbá ti ma dábírà ha mokáre láiyé mi
Destiny mi won ò lè change é
Ó n gbóná felifeli omo won ò lè cage é o
Kádàrá mi won ò lè change é
Wón kò lè fa owó ago séhìn ni but won ò lè kill é o
Destiny mi won ò lè change é
Ó n gbóná felifeli omo won ò lè cage é o
Kádàrá mi won ò lè change é
Wón kò lè fa owó ago séhìn ni but won ò lè kill é o
Àyànmó wa kòní tàsé wa
Kádàrá wa kòní gbàgbé wa
Nkan ta maje kòní kojá wa
Kádàrá wa kòní tàsé wa yeyeehiii
Bí òtá fé bí òtá kò moma gbébè
Ibù jókó ayòmi for sure mo ma débè
Àsìkò mi ìgbà mi maje kó dòbu
Jékí gbòngbò olà mi dilè mú kán málè fàátu
Moti pé nínú game yí
Àyàfi kólúwa ràn mí lówó aàní rógun kéèyí
Kín make owó ló ma pay yín
Respect pèlú accolade gan lóma earn yín
Se àdúrà kin se àmín
Tobá ju òkò kòní bàmí
Mi ò manage o kòní gbà mí
Àyànmò mi kòlè dàmí
Se àdúrà kin se àmín
Tobá ju òkò kòní bàmí
Mi ò manage o kòní gbà mí
Àyànmò mi kòlè dàmí
Cuz Ótipé tí moti ń babò
Ótipé tí moti ń lebò so ekími káàbò
Èbè ni mobè Olúwami jàre dáàbò
Gbémilékè aiyé kín ma ever jábó
Destiny mi won ò lè change é
Ó n gbóná felifeli omo won ò lè cage é o
Kádàrá mi won ò lè change é
Wón kò lè fa owó ago séhìn ni but won ò lè kill é o
Destiny mi won ò lè change é
Ó n gbóná felifeli omo won ò lè cage é o
Kádàrá mi won ò lè change é
Wón kò lè fa owó ago séhìn ni but won ò lè kill é o
Àyànmó wa kòní tàsé wa
Kádàrá wa kòní gbàgbé wa
Nkan ta maje kòní kojá wa
Kádàrá wa kòní tàsé wa yeyeehiii

Written by:
Victor Oguntoyinbo

Publisher:
Lyrics © O/B/O DistroKid

Lyrics powered by Lyric Find

Poptyofv featuring Tat Lyricsane

View Profile